notícias musicais

top 13 artistas

top 13 musicas

Confira a Letra Omoyeni

Ọmọ'yẹni, ọmọ'yẹni, mà ti d'àràbà s'ọ'nà
Ọmọ'yẹni, ọmọ'yẹni, d'ẹyẹ òkè tó nfò lẹlẹ

Olúborí l'ókè, olúborí n'ílẹ'
Olúborí l'ọ'nà, olúborí lókolódò

Ọmọ'yẹni, ọmọ'yẹni, d'ẹyẹ òkè tó nfò